MY YEAR OF GREAT ACHIEVEMENT
Psalms 119:116
“Uphold me according to Your word, that I may live; And do not let me be ashamed of my hope.” (NKJV)
“Gbé mi sókè gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ rẹ, kí èmi kí ó lè yè Má sì jẹ́ kí ojú ìrètí mi kí ó tì mí.” (BYO)